Ìfihàn 18:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Àwọn ọba ayé tó bá a ṣe ìṣekúṣe,* tí wọ́n sì jọ gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ láìnítìjú máa sunkún, ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí wọ́n lu ara wọn, tí wọ́n bá rí èéfín rẹ̀ nígbà tó ń jóná.
9 “Àwọn ọba ayé tó bá a ṣe ìṣekúṣe,* tí wọ́n sì jọ gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ láìnítìjú máa sunkún, ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí wọ́n lu ara wọn, tí wọ́n bá rí èéfín rẹ̀ nígbà tó ń jóná.