2 Ó sì fi ohùn tó le ké jáde pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá ti ṣubú,+ ó sì ti di ibi tí àwọn ẹ̀mí èṣù ń gbé àti ibi tí gbogbo ẹ̀mí àìmọ́* àti gbogbo ẹyẹ àìmọ́ tí a kórìíra ń lúgọ sí!+
9 “Àwọn ọba ayé tó bá a ṣe ìṣekúṣe,* tí wọ́n sì jọ gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ láìnítìjú máa sunkún, ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí wọ́n lu ara wọn, tí wọ́n bá rí èéfín rẹ̀ nígbà tó ń jóná.