Ìfihàn 18:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo gbọ́ ohùn míì láti ọ̀run, ó sọ pé: “Ẹ jáde kúrò nínú rẹ̀, ẹ̀yin èèyàn mi,+ tí ẹ kò bá fẹ́ pín nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ẹ kò bá sì fẹ́ gbà lára àwọn ìyọnu rẹ̀.+ 5 Torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ ti ga dé ọ̀run,+ Ọlọ́run sì ti rántí àwọn ìwà àìṣòdodo tó hù.*+
4 Mo gbọ́ ohùn míì láti ọ̀run, ó sọ pé: “Ẹ jáde kúrò nínú rẹ̀, ẹ̀yin èèyàn mi,+ tí ẹ kò bá fẹ́ pín nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ẹ kò bá sì fẹ́ gbà lára àwọn ìyọnu rẹ̀.+ 5 Torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ ti ga dé ọ̀run,+ Ọlọ́run sì ti rántí àwọn ìwà àìṣòdodo tó hù.*+