- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        28 Ìró àwọn tó ń sá lọ ń dún, Àwọn tó ń sá àsálà láti ilẹ̀ Bábílónì, Láti kéde ẹ̀san Jèhófà Ọlọ́run wa ní Síónì, Ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.+ 
 
-