Ìfihàn 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọ̀kan lára àwọn áńgẹ́lì méje tó ní abọ́ méje+ náà wá, ó sì sọ fún mi pé: “Wá, màá fi ìdájọ́ aṣẹ́wó ńlá tó jókòó lórí omi púpọ̀ hàn ọ́,+ Ìfihàn 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó sọ fún mi pé: “Àwọn omi tí o rí, níbi tí aṣẹ́wó náà jókòó sí, túmọ̀ sí àwọn èèyàn àti èrò rẹpẹtẹ àti àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn ahọ́n.*+
17 Ọ̀kan lára àwọn áńgẹ́lì méje tó ní abọ́ méje+ náà wá, ó sì sọ fún mi pé: “Wá, màá fi ìdájọ́ aṣẹ́wó ńlá tó jókòó lórí omi púpọ̀ hàn ọ́,+
15 Ó sọ fún mi pé: “Àwọn omi tí o rí, níbi tí aṣẹ́wó náà jókòó sí, túmọ̀ sí àwọn èèyàn àti èrò rẹpẹtẹ àti àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn ahọ́n.*+