Àìsáyà 44:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Wò ó! Ojú máa ti gbogbo àwọn alájọṣe rẹ̀!+ Èèyàn lásán ni àwọn oníṣẹ́ ọnà. Kí gbogbo wọn kóra jọ, kí wọ́n sì dúró. Jìnnìjìnnì máa bò wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n pa pọ̀.
11 Wò ó! Ojú máa ti gbogbo àwọn alájọṣe rẹ̀!+ Èèyàn lásán ni àwọn oníṣẹ́ ọnà. Kí gbogbo wọn kóra jọ, kí wọ́n sì dúró. Jìnnìjìnnì máa bò wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n pa pọ̀.