- 
	                        
            
            Jeremáyà 14:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        22 Ǹjẹ́ ìkankan lára àwọn òrìṣà lásánlàsàn tí àwọn orílẹ̀-èdè ń bọ lè rọ òjò, Àbí ṣé ọ̀run fúnra rẹ̀ pàápàá lè dá rọ ọ̀wààrà òjò? Ìwọ nìkan lo lè ṣe é, Jèhófà Ọlọ́run wa.+ A sì ní ìrètí nínú rẹ, Nítorí ìwọ nìkan ló ń ṣe gbogbo nǹkan yìí. 
 
-