ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 50:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí ìbínú Jèhófà, ẹnikẹ́ni kò ní gbé inú rẹ̀;+

      Á sì di ahoro látòkè délẹ̀.+

      Ẹnikẹ́ni tó bá ń kọjá lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ Bábílónì á wò ó, ẹ̀rù á bà á

      Á sì súfèé nítorí gbogbo ìyọnu rẹ̀.+

  • Jeremáyà 50:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 “Bí Ọlọ́run ṣe pa Sódómù àti Gòmórà+ àti àwọn ìlú tó yí wọn ká run,”+ ni Jèhófà wí, “kò ní sí ẹnì kankan tí á máa gbé ibẹ̀, kò sì ní sí èèyàn kankan tó máa tẹ̀ dó síbẹ̀.+

  • Ìfihàn 18:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Áńgẹ́lì kan tó lágbára wá gbé òkúta kan tó dà bí ọlọ ńlá sókè, ó sì jù ú sínú òkun, ó ní: “Báyìí la ṣe máa yára ju Bábílónì ìlú ńlá náà sísàlẹ̀, a ò sì ní rí i mọ́ láé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́