-
Àìsáyà 47:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
O máa ko àgbákò; o ò ní lè yẹ̀ ẹ́.
Ìparun òjijì máa dé bá ọ, irú èyí tí kò ṣẹlẹ̀ sí ọ rí.+
-
-
Jeremáyà 50:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Mo ti dẹkùn fún ọ, ó sì ti mú ọ, ìwọ Bábílónì,
Ìwọ kò sì mọ̀.
Wọ́n rí ọ, wọ́n sì gbá ọ mú,+
Torí pé Jèhófà ni o ta kò.
-
-
Jeremáyà 50:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ìdààmú ti bá a,
Ìrora bíi ti obìnrin tó ń rọbí.
-