Àìsáyà 48:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Gbọ́ èyí, ìwọ ilé Jékọ́bù,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Ísírẹ́lì pe ara yín +Àti ẹ̀yin tí ẹ jáde látinú omi* Júdà,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Jèhófà búra,+Tí ẹ sì ń ké pe Ọlọ́run Ísírẹ́lì,Bó tiẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe ní òtítọ́ àti òdodo.+
48 Gbọ́ èyí, ìwọ ilé Jékọ́bù,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Ísírẹ́lì pe ara yín +Àti ẹ̀yin tí ẹ jáde látinú omi* Júdà,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Jèhófà búra,+Tí ẹ sì ń ké pe Ọlọ́run Ísírẹ́lì,Bó tiẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe ní òtítọ́ àti òdodo.+