Àìsáyà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ pohùn réré ẹkún, torí ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé! Ó máa jẹ́ ọjọ́ ìparun látọ̀dọ̀ Olódùmarè.+