2 Àwọn Ọba 23:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹni ọdún mẹ́tàlélógún (23) ni Jèhóáhásì+ nígbà tó jọba, oṣù mẹ́ta ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútálì+ ọmọ Jeremáyà láti Líbínà.
31 Ẹni ọdún mẹ́tàlélógún (23) ni Jèhóáhásì+ nígbà tó jọba, oṣù mẹ́ta ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútálì+ ọmọ Jeremáyà láti Líbínà.