2 Kíróníkà 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Sólómọ́nì ṣe gbogbo nǹkan èlò+ ilé Ọlọ́run tòótọ́: pẹpẹ wúrà;+ àwọn tábìlì+ tí búrẹ́dì àfihàn wà lórí wọn;+ 2 Kíróníkà 4:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 àwọn ohun tí wọ́n fi ń pa fìtílà, àwọn abọ́, àwọn ife àti àwọn ìkóná tí a fi ògidì wúrà ṣe; ẹnu ọ̀nà ilé náà, àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ ti inú Ibi Mímọ́ Jù Lọ+ àti àwọn ilẹ̀kùn ilé tẹ́ńpìlì tí a fi wúrà ṣe.+
19 Sólómọ́nì ṣe gbogbo nǹkan èlò+ ilé Ọlọ́run tòótọ́: pẹpẹ wúrà;+ àwọn tábìlì+ tí búrẹ́dì àfihàn wà lórí wọn;+
22 àwọn ohun tí wọ́n fi ń pa fìtílà, àwọn abọ́, àwọn ife àti àwọn ìkóná tí a fi ògidì wúrà ṣe; ẹnu ọ̀nà ilé náà, àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ ti inú Ibi Mímọ́ Jù Lọ+ àti àwọn ilẹ̀kùn ilé tẹ́ńpìlì tí a fi wúrà ṣe.+