-
Jeremáyà 6:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:
“Wọ́n á fara balẹ̀ ṣa* èyí tó ṣẹ́ kù lára Ísírẹ́lì bí èso àjàrà tó kẹ́yìn.
Pa dà lọ ṣà wọ́n bí ẹni tó ń ṣa èso àjàrà lórí àwọn àjàrà.”
-