Ìsíkíẹ́lì 22:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Inú rẹ ni ọkùnrin kan ti bá ìyàwó ọmọnìkejì rẹ̀ ṣe ohun ìríra,+ ẹlòmíì hùwà àìnítìjú ní ti pé ó bá ìyàwó ọmọ rẹ̀ sùn, ẹlòmíì sì bá arábìnrin rẹ̀,+ tó jẹ́ ọmọ bàbá rẹ̀ lò pọ̀.+
11 Inú rẹ ni ọkùnrin kan ti bá ìyàwó ọmọnìkejì rẹ̀ ṣe ohun ìríra,+ ẹlòmíì hùwà àìnítìjú ní ti pé ó bá ìyàwó ọmọ rẹ̀ sùn, ẹlòmíì sì bá arábìnrin rẹ̀,+ tó jẹ́ ọmọ bàbá rẹ̀ lò pọ̀.+