Jeremáyà 23:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Ǹjẹ́ kì í ṣe bí iná ni ọ̀rọ̀ mi rí,”+ ni Jèhófà wí “àti bí òòlù irin* tó ń fọ́ àpáta sí wẹ́wẹ́?”+
29 “Ǹjẹ́ kì í ṣe bí iná ni ọ̀rọ̀ mi rí,”+ ni Jèhófà wí “àti bí òòlù irin* tó ń fọ́ àpáta sí wẹ́wẹ́?”+