Jeremáyà 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Gbogbo ilẹ̀ náà á di ahoro,+Àmọ́ mi ò ní pa á run pátápátá.