- 
	                        
            
            Diutarónómì 28:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 Ojú ọ̀run tó wà lókè orí rẹ máa di bàbà, ilẹ̀ tó sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ máa di irin.+ 24 Jèhófà máa sọ òjò ilẹ̀ rẹ di nǹkan lẹ́búlẹ́bú àti eruku tí á máa kù sórí rẹ láti ọ̀run títí o fi máa pa run. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 3:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Torí náà ni òjò kò fi rọ̀,+ Tí kò sì sí òjò ní ìgbà ìrúwé. 
 
-