ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 8:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ pé, ‘Ìgbà wo ni àjọ̀dún òṣùpá tuntun máa parí,+ ká lè ta àwọn hóró ọkà wa,

      Àti ìparí Sábáàtì,+ ká lè gbé hóró ọkà lọ fún títà?

      Ká lè sọ òṣùwọ̀n eéfà* di kékeré

      Kí a sì sọ ṣékélì* di ńlá,

      Kí a dọ́gbọ́n sí àwọn òṣùwọ̀n wa, kí a lè fi tanni jẹ;+

  • Míkà 6:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ṣé mo lè sọ pé ìwà* mi mọ́ tí mo bá ń lo òṣùwọ̀n èké

      Àti àpò ayédèrú òkúta òṣùwọ̀n?+

      12 Ìwà ipá kún ọwọ́ àwọn ọlọ́rọ̀ rẹ̀,

      Òpùrọ́ ni àwọn tó ń gbé inú rẹ̀;+

      Ahọ́n wọn ń tanni jẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́