-
Jeremáyà 44:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nítorí náà, ìrunú mi àti ìbínú mi tú jáde, ó sì jó bí iná ní àwọn ìlú Júdà àti ní àwọn ojú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì di àwókù àti ahoro bí wọ́n ṣe rí lónìí yìí.’+
-