-
Ìsíkíẹ́lì 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ìwà ipá ti hù, ó sì ti di ọ̀pá ìwà burúkú.+ Wọn ò ní yè bọ́, bẹ́ẹ̀ sì ni ọrọ̀ wọn, àwọn èèyàn àti òkìkí wọn kò sì ní yè bọ́.
-