Jeremáyà 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí náà, fi àwọn ọmọ wọn fún ìyàn,Sì fi àwọn fúnra wọn fún idà.+ Kí àwọn ìyàwó wọn ṣòfò ọmọ, kí wọ́n sì di opó.+ Kí àjàkálẹ̀ àrùn pa àwọn ọkùnrin wọn,Kí idà sì pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn lójú ogun.+
21 Torí náà, fi àwọn ọmọ wọn fún ìyàn,Sì fi àwọn fúnra wọn fún idà.+ Kí àwọn ìyàwó wọn ṣòfò ọmọ, kí wọ́n sì di opó.+ Kí àjàkálẹ̀ àrùn pa àwọn ọkùnrin wọn,Kí idà sì pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn lójú ogun.+