Ìsíkíẹ́lì 22:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Inú rẹ ni wọ́n ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n lè ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.+ Ò ń yáni lówó èlé,+ ò ń jẹ èrè* lórí owó tí o yáni, o sì ń fipá gba owó lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ.+ Àní, o ti gbàgbé mi pátápátá,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
12 Inú rẹ ni wọ́n ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n lè ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.+ Ò ń yáni lówó èlé,+ ò ń jẹ èrè* lórí owó tí o yáni, o sì ń fipá gba owó lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ.+ Àní, o ti gbàgbé mi pátápátá,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.