Jeremáyà 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi.+ Torí pé wọ́n ń rú ẹbọ* sí àwọn ohun tí kò ní láárí,+Wọ́n ń mú kí àwọn èèyàn fẹsẹ̀ kọ ní ọ̀nà wọn, àwọn ojú ọ̀nà àtijọ́,+Láti rìn ní ọ̀nà gbágungbàgun, ọ̀nà tí kò dán, tí kò sì tẹ́jú,*
15 Àmọ́ àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi.+ Torí pé wọ́n ń rú ẹbọ* sí àwọn ohun tí kò ní láárí,+Wọ́n ń mú kí àwọn èèyàn fẹsẹ̀ kọ ní ọ̀nà wọn, àwọn ojú ọ̀nà àtijọ́,+Láti rìn ní ọ̀nà gbágungbàgun, ọ̀nà tí kò dán, tí kò sì tẹ́jú,*