Àìsáyà 58:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 “Fi gbogbo ẹnu kígbe; má ṣe dákẹ́! Gbé ohùn rẹ sókè bíi fèrè. Kéde ọ̀tẹ̀ àwọn èèyàn mi fún wọn,+Kí o sọ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ilé Jékọ́bù fún wọn.
58 “Fi gbogbo ẹnu kígbe; má ṣe dákẹ́! Gbé ohùn rẹ sókè bíi fèrè. Kéde ọ̀tẹ̀ àwọn èèyàn mi fún wọn,+Kí o sọ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ilé Jékọ́bù fún wọn.