Àìsáyà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí kún ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n ń forí balẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn,Fún ohun tí wọ́n fi ìka ara wọn ṣe.
8 Àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí kún ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n ń forí balẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn,Fún ohun tí wọ́n fi ìka ara wọn ṣe.