Sekaráyà 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ wọn ò fetí sílẹ̀,+ agídí wọn mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí mi,+ wọ́n sì di etí wọn kí wọ́n má bàa gbọ́.+
11 Àmọ́ wọn ò fetí sílẹ̀,+ agídí wọn mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí mi,+ wọ́n sì di etí wọn kí wọ́n má bàa gbọ́.+