Jeremáyà 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nítorí mo gbọ́ ohùn kan tó dà bíi ti obìnrin tó ń ṣàìsàn,Ìdààmú bíi ti obìnrin tó ń rọbí àkọ́bí ọmọ rẹ̀,Ohùn ọmọbìnrin Síónì tó ń mí gúlegúle. Bó ṣe tẹ́ àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, ó ń sọ pé:+ “Mo gbé, àárẹ̀ ti mú mi* nítorí àwọn apààyàn!”
31 Nítorí mo gbọ́ ohùn kan tó dà bíi ti obìnrin tó ń ṣàìsàn,Ìdààmú bíi ti obìnrin tó ń rọbí àkọ́bí ọmọ rẹ̀,Ohùn ọmọbìnrin Síónì tó ń mí gúlegúle. Bó ṣe tẹ́ àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, ó ń sọ pé:+ “Mo gbé, àárẹ̀ ti mú mi* nítorí àwọn apààyàn!”