-
Jeremáyà 15:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Màá mú kí àwọn opó wọn pọ̀ ju iyanrìn òkun lọ.
Màá mú apanirun wá bá wọn ní ọ̀sán gangan, yóò wá bá àwọn ìyá àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin.
Màá sì mú ìrúkèrúdò àti ẹ̀rù wá bá wọn lójijì.
-