Ìsíkíẹ́lì 24:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “‘Ìwà àìnítìjú rẹ ló mú kí o di aláìmọ́.+ Mo wẹ̀ ọ́ títí kí o lè mọ́, àmọ́ ìwà àìmọ́ rẹ kò kúrò. Ìwọ kì yóò mọ́ títí ìbínú mi sí ọ fi máa rọlẹ̀.+
13 “‘Ìwà àìnítìjú rẹ ló mú kí o di aláìmọ́.+ Mo wẹ̀ ọ́ títí kí o lè mọ́, àmọ́ ìwà àìmọ́ rẹ kò kúrò. Ìwọ kì yóò mọ́ títí ìbínú mi sí ọ fi máa rọlẹ̀.+