Àìsáyà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jèhófà máa dá àwọn àgbààgbà àtàwọn olórí àwọn èèyàn rẹ̀ lẹ́jọ́. “Ẹ ti dáná sun ọgbà àjàrà. Ohun tí ẹ jí lọ́dọ̀ aláìní sì wà nínú àwọn ilé yín.+ Míkà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Oko olóko wọ̀ wọ́n lójú, wọ́n sì gbà á;+Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n gba ilé onílé;Wọ́n fi jìbìtì gba ilé mọ́ onílé lọ́wọ́,+Wọ́n gba ogún lọ́wọ́ ẹni tó ni ín.
14 Jèhófà máa dá àwọn àgbààgbà àtàwọn olórí àwọn èèyàn rẹ̀ lẹ́jọ́. “Ẹ ti dáná sun ọgbà àjàrà. Ohun tí ẹ jí lọ́dọ̀ aláìní sì wà nínú àwọn ilé yín.+
2 Oko olóko wọ̀ wọ́n lójú, wọ́n sì gbà á;+Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n gba ilé onílé;Wọ́n fi jìbìtì gba ilé mọ́ onílé lọ́wọ́,+Wọ́n gba ogún lọ́wọ́ ẹni tó ni ín.