Mátíù 21:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó sọ fún wọn pé: “A ti kọ ọ́ pé, ‘A ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà,’+ àmọ́ ẹ̀ ń sọ ọ́ di ihò àwọn olè.”+ Máàkù 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó ń kọ́ wọn, ó sì ń sọ fún wọn pé: “Ṣebí a ti kọ ọ́ pé, ‘A ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà fún gbogbo orílẹ̀-èdè’?+ Àmọ́ ẹ ti sọ ọ́ di ihò àwọn olè.”+ Lúùkù 19:45, 46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ó wá wọnú tẹ́ńpìlì, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í lé àwọn tó ń tajà síta,+ 46 ó ń sọ fún wọn pé: “A ti kọ ọ́ pé, ‘A ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà,’+ àmọ́ ẹ ti sọ ọ́ di ihò àwọn olè.”+
13 Ó sọ fún wọn pé: “A ti kọ ọ́ pé, ‘A ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà,’+ àmọ́ ẹ̀ ń sọ ọ́ di ihò àwọn olè.”+
17 Ó ń kọ́ wọn, ó sì ń sọ fún wọn pé: “Ṣebí a ti kọ ọ́ pé, ‘A ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà fún gbogbo orílẹ̀-èdè’?+ Àmọ́ ẹ ti sọ ọ́ di ihò àwọn olè.”+
45 Ó wá wọnú tẹ́ńpìlì, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í lé àwọn tó ń tajà síta,+ 46 ó ń sọ fún wọn pé: “A ti kọ ọ́ pé, ‘A ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà,’+ àmọ́ ẹ ti sọ ọ́ di ihò àwọn olè.”+