-
Jeremáyà 26:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Jeremáyà wá sọ fún gbogbo àwọn ìjòyè àti gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Jèhófà ló rán mi láti sọ gbogbo àsọtẹ́lẹ̀ tí ẹ ti gbọ́ nípa ilé yìí àti nípa ìlú yìí.+
-