Jeremáyà 7:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn tí wọ́n ń sọ pé, ‘Èyí ni* tẹ́ńpìlì Jèhófà, tẹ́ńpìlì Jèhófà, tẹ́ńpìlì Jèhófà!’+
4 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn tí wọ́n ń sọ pé, ‘Èyí ni* tẹ́ńpìlì Jèhófà, tẹ́ńpìlì Jèhófà, tẹ́ńpìlì Jèhófà!’+