Jeremáyà 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà náà, Jèhófà sọ fún mi pé: “Bí Mósè àti Sámúẹ́lì bá tiẹ̀ dúró níwájú mi,+ mi ò ní ṣojúure sí* àwọn èèyàn yìí. Lé wọn kúrò níwájú mi, kí wọ́n máa lọ.
15 Nígbà náà, Jèhófà sọ fún mi pé: “Bí Mósè àti Sámúẹ́lì bá tiẹ̀ dúró níwájú mi,+ mi ò ní ṣojúure sí* àwọn èèyàn yìí. Lé wọn kúrò níwájú mi, kí wọ́n máa lọ.