Hósíà 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí Ísírẹ́lì ti di alágídí bíi màlúù tó lágídí.+ Ǹjẹ́ Jèhófà yóò ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn bí ọmọ àgbò nínú ibi ìjẹko tó tẹ́jú?* Sekaráyà 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n mú kí ọkàn wọn le bíi dáyámọ́ǹdì,*+ wọn ò sì tẹ̀ lé òfin* àti ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fi ẹ̀mí rẹ̀ sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì àtijọ́.+ Torí náà, inú bí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun gan-an.”+
16 Nítorí Ísírẹ́lì ti di alágídí bíi màlúù tó lágídí.+ Ǹjẹ́ Jèhófà yóò ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn bí ọmọ àgbò nínú ibi ìjẹko tó tẹ́jú?*
12 Wọ́n mú kí ọkàn wọn le bíi dáyámọ́ǹdì,*+ wọn ò sì tẹ̀ lé òfin* àti ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fi ẹ̀mí rẹ̀ sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì àtijọ́.+ Torí náà, inú bí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun gan-an.”+