Hósíà 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Màá dá àwọn ọgbà àjàrà rẹ̀ pa dà fún un láti ìgbà náà lọ,+Màá sì fi Àfonífojì* Ákórì+ ṣe ọ̀nà ìrètí fún un;Yóò dáhùn níbẹ̀ bíi ti ìgbà èwe rẹ̀,Bíi ti ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+
15 Màá dá àwọn ọgbà àjàrà rẹ̀ pa dà fún un láti ìgbà náà lọ,+Màá sì fi Àfonífojì* Ákórì+ ṣe ọ̀nà ìrètí fún un;Yóò dáhùn níbẹ̀ bíi ti ìgbà èwe rẹ̀,Bíi ti ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+