-
Jeremáyà 19:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Bí màá ṣe fọ́ àwọn èèyàn yìí àti ìlú yìí nìyẹn bí ìgbà tí èèyàn fọ́ ohun tí amọ̀kòkò ṣe mọ́lẹ̀, tí kò fi ní àtúnṣe mọ́. Wọ́n á sì sin òkú ní Tófétì títí kò fi ní sí àyè mọ́ láti sìnkú.”’+
-