ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 56:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ajá tó ń jẹun wọ̀mùwọ̀mù* ni wọ́n;

      Wọn kì í yó.

      Olùṣọ́ àgùntàn tí kò lóye ni wọ́n.+

      Gbogbo wọn ti bá ọ̀nà tiwọn lọ;

      Àní ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ń wá èrè tí kò tọ́ fún ara rẹ̀, ó ń sọ pé:

  • Ìsíkíẹ́lì 33:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Wọn yóò rọ́ wá bá ọ, kí wọ́n lè jókòó síwájú rẹ bí èèyàn mi; wọ́n á sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ, àmọ́ wọn ò ní ṣe ohun tí wọ́n gbọ́.+ Wọ́n ń fi ẹnu wọn sọ̀rọ̀ dídùn fún ọ,* àmọ́ bí wọ́n ṣe máa jèrè tí kò tọ́ ló wà lọ́kàn wọn.

  • Míkà 3:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+

      Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+

      Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+

      Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé:

      “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+

      Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́