-
Jeremáyà 8:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Kí nìdí tí a fi jókòó síbí?
Ẹ jẹ́ ká kóra jọ, ká wọnú àwọn ìlú olódi,+ ká sì ṣègbé síbẹ̀.
-
-
Jeremáyà 23:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ sí àwọn wòlíì náà nìyí:
Nítorí láti ọ̀dọ̀ àwọn wòlíì Jerúsálẹ́mù ni ìpẹ̀yìndà ti tàn káàkiri ilẹ̀ náà.”
-