ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 4:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Nítorí mo gbọ́ ohùn kan tó dà bíi ti obìnrin tó ń ṣàìsàn,

      Ìdààmú bíi ti obìnrin tó ń rọbí àkọ́bí ọmọ rẹ̀,

      Ohùn ọmọbìnrin Síónì tó ń mí gúlegúle.

      Bó ṣe tẹ́ àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, ó ń sọ pé:+

      “Mo gbé, àárẹ̀ ti mú mi* nítorí àwọn apààyàn!”

  • Ìsíkíẹ́lì 7:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àwọn tó bá jàjà bọ́ yóò sá lọ sórí àwọn òkè, kálukú wọn á sì ké tẹ̀dùntẹ̀dùn torí àṣìṣe rẹ̀ bí àwọn àdàbà inú àfonífojì.+

  • Míkà 1:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Torí èyí, màá pohùn réré ẹkún, màá sì hu;+

      Èmi yóò rìn láìwọ bàtà àti ní ìhòòhò.+

      Màá pohùn réré ẹkún bí ajáko,*

      Èmi yóò sì ṣọ̀fọ̀ bí ògòǹgò.

       9 Torí ọgbẹ́ rẹ̀ kò lè jinná;+

      Ó ti dé Júdà lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún.+

      Egbò náà ti ràn dé ẹnubodè àwọn èèyàn mi, dé Jerúsálẹ́mù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́