Ìdárò 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn èèyàn ń ké jáde sí wọn pé, “Ẹ kúrò! Ẹ̀yin aláìmọ́! Ẹ kúrò! Ẹ kúrò! Ẹ má fọwọ́ kàn wá!” Nítorí wọn ò rí ilé gbé, wọ́n sì ń rìn kiri. Àwọn èèyàn ń sọ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè pé: “Wọn ò lè gbé ibí yìí pẹ̀lú wa.*+ Míkà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ dìde, kí ẹ máa lọ, torí ibí kì í ṣe ibi ìsinmi. Torí ìwà àìmọ́ yín,+ ẹ máa pa run, ìparun pátápátá.+
15 Àwọn èèyàn ń ké jáde sí wọn pé, “Ẹ kúrò! Ẹ̀yin aláìmọ́! Ẹ kúrò! Ẹ kúrò! Ẹ má fọwọ́ kàn wá!” Nítorí wọn ò rí ilé gbé, wọ́n sì ń rìn kiri. Àwọn èèyàn ń sọ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè pé: “Wọn ò lè gbé ibí yìí pẹ̀lú wa.*+
10 Ẹ dìde, kí ẹ máa lọ, torí ibí kì í ṣe ibi ìsinmi. Torí ìwà àìmọ́ yín,+ ẹ máa pa run, ìparun pátápátá.+