1 Kọ́ríńtì 1:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 kí ó lè rí bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹni tó bá ń yangàn, kó máa yangàn nínú Jèhófà.”*+ 2 Kọ́ríńtì 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Ṣùgbọ́n ẹni tó bá fẹ́ yangàn, kí ó máa fi Jèhófà* yangàn.”+