Sáàmù 99:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù. Hósíà 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí pé ìfẹ́ tí kì í yẹ̀* ni inú mi dùn sí, kì í ṣe ẹbọÀti ìmọ̀ nípa Ọlọ́run dípò odindi ẹbọ sísun.+ Míkà 6:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó ti sọ ohun tó dára fún ọ, ìwọ ọmọ aráyé. Kí sì ni Jèhófà fẹ́ kí o ṣe?* Bí kò ṣe pé kí o ṣe ìdájọ́ òdodo,*+ kí o mọyì jíjẹ́ adúróṣinṣin,*+Kí o sì mọ̀wọ̀n ara rẹ+ bí o ṣe ń bá Ọlọ́run rẹ rìn!+ Míkà 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+
4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù.
6 Nítorí pé ìfẹ́ tí kì í yẹ̀* ni inú mi dùn sí, kì í ṣe ẹbọÀti ìmọ̀ nípa Ọlọ́run dípò odindi ẹbọ sísun.+
8 Ó ti sọ ohun tó dára fún ọ, ìwọ ọmọ aráyé. Kí sì ni Jèhófà fẹ́ kí o ṣe?* Bí kò ṣe pé kí o ṣe ìdájọ́ òdodo,*+ kí o mọyì jíjẹ́ adúróṣinṣin,*+Kí o sì mọ̀wọ̀n ara rẹ+ bí o ṣe ń bá Ọlọ́run rẹ rìn!+
18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+