Jeremáyà 49:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Sí àwọn ọmọ Ámónì,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ṣé Ísírẹ́lì kò ní ọmọ ni? Ṣé kò ní ẹni tó máa jogún rẹ̀ ni? Kí ló dé tí Málíkámù+ fi gba Gádì?+ Tí àwọn èèyàn rẹ̀ sì ń gbé inú àwọn ìlú Ísírẹ́lì?” Ìsíkíẹ́lì 25:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọmọ èèyàn, yíjú sọ́dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì,+ kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí wọn.+
49 Sí àwọn ọmọ Ámónì,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ṣé Ísírẹ́lì kò ní ọmọ ni? Ṣé kò ní ẹni tó máa jogún rẹ̀ ni? Kí ló dé tí Málíkámù+ fi gba Gádì?+ Tí àwọn èèyàn rẹ̀ sì ń gbé inú àwọn ìlú Ísírẹ́lì?”