Léfítíkù 26:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Èmi náà sì kẹ̀yìn sí wọn,+ torí mo mú wọn wá sí ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn.+ “‘Bóyá nígbà yẹn, wọ́n á rẹ ọkàn wọn tí wọn ò kọ nílà* wálẹ̀,+ wọ́n á sì wá jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Jeremáyà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ kọ ara yín nílà* fún Jèhófà,Ẹ sì kọlà fún* ọkàn yín,+Ẹ̀yin èèyàn Júdà àti ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerúsálẹ́mù,Kí ìbínú mi má bàa ru jáde bí ináKí ó sì máa jó, tí kò fi ní sí ẹni tó lè pa á,Nítorí ìwà ibi yín.”+
41 Èmi náà sì kẹ̀yìn sí wọn,+ torí mo mú wọn wá sí ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn.+ “‘Bóyá nígbà yẹn, wọ́n á rẹ ọkàn wọn tí wọn ò kọ nílà* wálẹ̀,+ wọ́n á sì wá jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.
4 Ẹ kọ ara yín nílà* fún Jèhófà,Ẹ sì kọlà fún* ọkàn yín,+Ẹ̀yin èèyàn Júdà àti ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerúsálẹ́mù,Kí ìbínú mi má bàa ru jáde bí ináKí ó sì máa jó, tí kò fi ní sí ẹni tó lè pa á,Nítorí ìwà ibi yín.”+