Àìsáyà 46:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n gbé e sí èjìká wọn,+Wọ́n gbé e, wọ́n sì fi sí àyè rẹ̀, ṣe ló kàn dúró síbẹ̀. Kì í kúrò ní àyè rẹ̀.+ Wọ́n ké sí i, àmọ́ kò dáhùn;Kò lè gba ẹnikẹ́ni nínú wàhálà.+
7 Wọ́n gbé e sí èjìká wọn,+Wọ́n gbé e, wọ́n sì fi sí àyè rẹ̀, ṣe ló kàn dúró síbẹ̀. Kì í kúrò ní àyè rẹ̀.+ Wọ́n ké sí i, àmọ́ kò dáhùn;Kò lè gba ẹnikẹ́ni nínú wàhálà.+