Sáàmù 89:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ta ló wà ní ọ̀run tí a lè fi wé Jèhófà?+ Èwo nínú àwọn ọmọ Ọlọ́run+ ló dà bíi Jèhófà? Dáníẹ́lì 4:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Kò ka gbogbo àwọn tó ń gbé ayé sí nǹkan kan, ohun tó bá sì wù ú ló ń ṣe láàárín àwọn ọmọ ogun ọ̀run àti àwọn tó ń gbé ayé. Kò sí ẹni tó lè dá a dúró*+ tàbí kó sọ fún un pé, ‘Kí lo ṣe yìí?’+
35 Kò ka gbogbo àwọn tó ń gbé ayé sí nǹkan kan, ohun tó bá sì wù ú ló ń ṣe láàárín àwọn ọmọ ogun ọ̀run àti àwọn tó ń gbé ayé. Kò sí ẹni tó lè dá a dúró*+ tàbí kó sọ fún un pé, ‘Kí lo ṣe yìí?’+