Àìsáyà 44:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kò sí ẹni tó rò ó nínú ọkàn rẹ̀,Tó ní ìmọ̀ tàbí òye, pé: “Mo ti dáná sun ìdajì rẹ̀,Ẹyin iná rẹ̀ ni mo fi yan búrẹ́dì, tí mo sì fi yan ẹran tí màá jẹ. Ṣé ó wá yẹ kí n fi èyí tó kù ṣe ohun ìríra?+ Ṣé ó yẹ kí n máa sin ìtì igi* tí mo gé lára igi?”
19 Kò sí ẹni tó rò ó nínú ọkàn rẹ̀,Tó ní ìmọ̀ tàbí òye, pé: “Mo ti dáná sun ìdajì rẹ̀,Ẹyin iná rẹ̀ ni mo fi yan búrẹ́dì, tí mo sì fi yan ẹran tí màá jẹ. Ṣé ó wá yẹ kí n fi èyí tó kù ṣe ohun ìríra?+ Ṣé ó yẹ kí n máa sin ìtì igi* tí mo gé lára igi?”