Àìsáyà 42:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 A máa dá wọn pa dà, ojú sì máa tì wọ́n gidigidi,Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé ère gbígbẹ́,Àwọn tó ń sọ fún àwọn ère onírin* pé: “Ẹ̀yin ni ọlọ́run wa.”+ Àìsáyà 44:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Wò ó! Ojú máa ti gbogbo àwọn alájọṣe rẹ̀!+ Èèyàn lásán ni àwọn oníṣẹ́ ọnà. Kí gbogbo wọn kóra jọ, kí wọ́n sì dúró. Jìnnìjìnnì máa bò wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n pa pọ̀.
17 A máa dá wọn pa dà, ojú sì máa tì wọ́n gidigidi,Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé ère gbígbẹ́,Àwọn tó ń sọ fún àwọn ère onírin* pé: “Ẹ̀yin ni ọlọ́run wa.”+
11 Wò ó! Ojú máa ti gbogbo àwọn alájọṣe rẹ̀!+ Èèyàn lásán ni àwọn oníṣẹ́ ọnà. Kí gbogbo wọn kóra jọ, kí wọ́n sì dúró. Jìnnìjìnnì máa bò wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n pa pọ̀.